CCC HYMN BOOK

CCC Hymn 357 — Yorùbá

1: Jesu ni ayọ mi Jesu ni ayọ mi Ayọ ti aye ko le fọwọ bo Jesu ni ayọ mi. 2: Jesu ni ayọ mi Jesu ni ayọ mi Ayọ ti aye ko le ridi rẹ Jesu ni ayọ mi. 3: Ayọ otitọ ni Ayọ otitọ ni Ayọ ayeraye ni temi Jesu ni ayọ mi. Amin

← Browse CCC hymns