CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 392 — Yorùbá
Ẹ fọpẹ fun Oluwa Ọlọrun Ijọ mimọ Ti ko jẹ kawa ṣegbe Wa fun igbala wa Ṣe igbọran ẹyin ẹlẹsẹ Lati rigbala ọfẹ To s’eleri rẹ fun yin Ẹke halleluyah Halleluyah! Halleluyah! Halleluyah si Orukọ Rẹ. Amin