CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 472 — Yorùbá
1. MO feri O, Olorun, Mo feri O, Olorun Mo feri Olorun, ninu ayo nla. 2. Sanu fun wa, Olorun, Sanu fun wa, Olorun, Sanu fun wa, Ka le w’ole Ogo. 3. Segun fun wa, Olorun, Segun fun wa, Olorun, Segun fun wa, ka le wole Ogo. Amin
