CCC HYMN BOOK

CCC Hymn 478 — Yorùbá

Bi gbogbo aye ditẹ mọ wa, Wọn gbọdọ tẹriba fun Oluwa Ẹyin ọmọ Ijọ Mimọ E dide ki ẹ yin Oluwa Halleluya ni orin wa Halleluya wa ninu ise wa Bi aye fẹ bi aye kọ Wọn tẹriba fun Oluwa Halleluya ni orin wa Halleluya wa ninu ise wa Bi aye fẹ bi aye kọ Wọn tẹriba fun Kristi. Amin

← Browse CCC hymns