CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 492 — Yorùbá
KI l'oruko Re, Iyanu, Iyanu, Kin' ise Re Iyanu, Iyanu, Oba to la’ju afoju, Iyanu, Iyanu, Oba to j’oku dide, Iyanu, Iyanu, Olugbala Ijo Mimo, Iyanu, Iyanu, Oba tin segun fun ni, Iyanu, Iyanu Kini ise Re, Iyanu, Iyanu, Ki l'oruko Re, lyanu lyanu. Amin
