CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 556 — Yorùbá
1: Olugbala na de Kristi nbọ wa Oludajọ aye O mbọ wa kankan 2: Ara ẹ yipada Ara ẹ yipada Yipada, ẹ yipada Satani gbode 3: Ajagun sẹgun ọrun Ajagun sẹgun ọrun W’a sẹgun satani Ninu ‘jọ mimọ. Amin