CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 601 — Yorùbá
1. ISE aiye yi lo sopin, Ise aiye osi yi, E je ka gba Oluwa gbo, Ka le gbade iye. 2. Ise Oluwa Iyanu, Eje ka mura si, Ise Oluwa Ogo ni, Ka le nibugbe loke. Amin