CCC HYMN BOOK

CCC Hymn 637 — Yorùbá

1: Jesu yi, Ẹmi Mimọ ni, Ọkan Mimọ ni, Ọba Iye ni, Ẹni ba fẹ sin Jesu Gbọdọ tọna to mọ rekete. 2: Jesu yi, Ẹmi Mimọ ni, Ọkan Mimọ ni, Ọba Iye ni, Ẹni ba fẹ sin Jesu a tọna To mọ rekete. Amin

← Browse CCC hymns