CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 771 — Yorùbá
1. Mo mbe ninu ododo Fun dapo awon eni mimo Ewa ninu idapo Titi emi o fi pada wa. 2. Emi kristi lo nso yi P’emi o wa danda lotito Lati wa se idajo aiye Lasi ko ikehin. Amin