CCC HYMN BOOK

CCC Hymn 777 — Yorùbá

1: Imọlẹ ni Jesu wa To fọ’lọrun Baba han Fun ‘jọ mimọ lat’ọrun wa Kawa le mọ titọ bi ifẹ Rẹ 2: Ọlọrun Baba wa da ‘ye Ati ọrun mimọ pẹlu Oda ‘niyan laworan Rẹ Isẹ ọwọ Ọlọrun wan i 3: Ijọ mimọ ẹ bu sayọ Ki celestial jumọ gbe ‘rin Fo’go nla lat’ọrun wa. Amin

← Browse CCC hymns