CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 794 — Yorùbá
JESU Omo Olorun gbadura fun wa, Jesu Omo Olorun, gbadura fun wa Jowo fun we l’emi Mimo, Fun wa l’ogo tire, Funwa ni agbara nla Omo olorun. Amin