CCC HYMN BOOK

CCC Hymn 829 — Yorùbá

JESU awa de sinu Ile Re, Wa sarin wa lati bukun wa, Omode niwa, awa ko mokan, Gbowo Re le wa, si sure funwa, Elese ni wa, awa ko mokan, Gbo owo Re le wa, si sanu ‘funwa, Dari ese ji wa, So wa di Mimo, Gbo owo re le wa si fa wa mora. Amin

← Browse CCC hymns