CCC HYMN BOOK
CCC Hymn 852 — Yorùbá
ABI Kristi fun wa loni ni Bethlehem, Awon ‘rawo Orun, Won mbu si ayo, Awon ‘rawo Orun, Won mbu si ayo, F’Olugbala to wa, Lati ko ese aiye lo, F’Olugbala to wa, Lati ko ese aiye lo, Enyin Angeli Mimo t’Orun, E bu sayo pelu, Awon ‘rawo mimo t’Orun. Amin
